Ope pataki fun awon iko igbinmo ti won se abewo si odo iya wa abileko ajoke ewa ede ni ojo kokandinlogbon osu kini odun 29/1/2026 ojo Thursday lati bawo soro Lori eto idije akoni Iran omo alade ti iya wa ajoke ewa ede si nfi nda wa loju pe awon se gbogbo ohun to to ati eyi to ye layi gba owo kankan aki eyin igbinmo ti e lo a de dupe pupo lowo iya wa ewa ede a mo lore ooo.